YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 Ìwé Míkà Orí 1 2 3 4 5 6 7 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Samáríà àti Júdà (1-16) Ẹ̀ṣẹ̀ àti ọ̀tẹ̀ ló fa wàhálà náà (5) 2 Àwọn tó ń ni ẹlòmíì lára gbé! (1-11) Ọlọ́run tún mú kí Ísírẹ́lì wà ní ìṣọ̀kan (12, 13) Ariwo àwọn èèyàn yóò gba ilẹ̀ náà kan (12) 3 Ọlọ́run bá àwọn olórí àti àwọn wòlíì wí (1-12) Ẹ̀mí Jèhófà fún Míkà ní agbára (8) Àwọn àlùfáà ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni (11) Jerúsálẹ́mù yóò di àwókù ilé (12) 4 Òkè Jèhófà yóò ga ju àwọn yòókù lọ (1-5) Wọ́n á fi idà rọ ohun ìtúlẹ̀ (3) “Àwa yóò máa rìn ní orúkọ Jèhófà” (5) Ọlọ́run yóò mú kí Síónì pa dà di alágbára (6-13) 5 Alákòóso kan yóò lágbára ní gbogbo ayé (1-6) Alákòóso náà yóò wá láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù (2) Àwọn tó ṣẹ́ kù yóò dà bí ìrì àti bíi kìnnìún (7-9) Ọlọ́run máa fọ ilẹ̀ náà mọ́ (10-15) 6 Ọlọ́run pe Ísírẹ́lì lẹ́jọ́ (1-5) Kí ni Jèhófà fẹ́? (6-8) Ìdájọ́ òdodo, ìṣòtítọ́, ìrẹ̀lẹ̀ (8) Ẹ̀bi Ísírẹ́lì àti ìyà tí wọ́n máa jẹ (9-16) 7 Ìwàkiwà Ísírẹ́lì (1-6) “Ará ilé ẹni ni ọ̀tá ẹni” (6) “Màá dúró de Ọlọ́run” (7) Ọlọ́run dá àwọn èèyàn rẹ̀ láre (8-13) Míkà gbàdúrà, ó sì yin Ọlọ́run (14-20) Jèhófà dáhùn (15-17) ‘Ta ló dà bíi Jèhófà?’ (18) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Míkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Míkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Míkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Míkà ojú ìwé 1256