Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hébérù
Wàá rí bí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ṣe jẹ́ káwọn Kristẹni tó jẹ́ Júù rí i pé àwọn nǹkan ti ọ̀run ni ìjọsìn wọn dá lé lórí. Èyí sì sàn ju ìjọsìn àwọn Júù lọ.