YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 Lẹ́tà Kìíní sí Àwọn Ará Tẹsalóníkà Orí 1 2 3 4 5 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1) Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Tẹsalóníkà (2-10) 2 Iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ní Tẹsalóníkà (1-12) Àwọn ará Tẹsalóníkà gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (13-16) Àárò àwọn ará Tẹsalóníkà ń sọ Pọ́ọ̀lù (17-20) 3 Ojú Pọ́ọ̀lù wà lọ́nà bó ṣe ń dúró ní Áténì (1-5) Ìròyìn tó ń tuni nínú tí Tímótì mú wá (6-10) Àdúrà fún àwọn ará Tẹsalóníkà (11-13) 4 Ìkìlọ̀ lórí ìṣekúṣe (1-8) Ẹ túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara yín (9-12) “Ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀” (11) Àwọn tó kú nínú Kristi ló máa kọ́kọ́ dìde (13-18) 5 Ọjọ́ Jèhófà ń bọ̀ (1-5) “Àlàáfíà àti ààbò!” (3) Ẹ wà lójúfò, ẹ máa ronú bó ṣe tọ́ (6-11) Ọ̀rọ̀ ìyànjú (12-24) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (25-28) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 1 Tẹsalóníkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 1 Tẹsalóníkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 1 Tẹsalóníkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 1 Tẹsalóníkà ojú ìwé 1574-1575