ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ January 2025
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti March 3–April 6, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 2
Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Máa Bọlá fún Ìyàwó Yín
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 10-16, 2025.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3
Máa Ṣe Ìpinnu Táá Múnú Jèhófà Dùn
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti March 17-23, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4
Kí La Kọ́ Nínú Ìràpadà Tí Jésù Ṣe?
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 24-30, 2025.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 5
Bá A Ṣe Ń Jàǹfààní Ìfẹ́ Tí Jèhófà Fi Hàn sí Wa
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 31–April 6, 2025.
Àwòrán Ń Jẹ́ Ká Rántí Ohun Tá A Kọ́
Tó o bá ń yàwòrán ohun tó ò ń kọ́ sórí ìwé, wàá túbọ̀ máa rántí ẹ̀.