ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ March 2024
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti May 6–June 9, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 9
Ṣé O Ti Ṣe Tán Láti Ya Ara Ẹ Sí Mímọ́ fún Jèhófà?
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 6-12, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 10
“Máa Tẹ̀ Lé” Jésù, Lẹ́yìn Tó O Bá Ṣèrìbọmi
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 13-19, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 11
Máa Sin Jèhófà Nìṣó Táwọn Nǹkan Kan Bá Já Ẹ Kulẹ̀
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 20-26, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 12
Sá fún Òkùnkùn—Wá Sínú Ìmọ́lẹ̀
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 27–June 2, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 13
Kí Ló Máa Mú Kó Dá Ẹ Lójú Pé Inú Jèhófà Dùn Sí Ẹ?
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 3-9, 2024.
Báwo Ni Jèhófà Ṣe Ń Dárí Jini Kí Jésù Tó San Ìràpadà?
Báwo wá ni Jèhófà ṣe ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini kí Jésù tó san ìràpadà, síbẹ̀ tí Jèhófà ṣì jẹ́ onídàájọ́ òdodo?