ILÉ ÌṢỌ́ No. 6 2016 | Àwọn Wo Ló Ń Gbé Ní Ọ̀run?
Rí àwọn nǹkan tí a kò lè fojú lásán rí látinú Bíbélì.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Àwọn Ìran Tó Sọ Àwọn Tó Ń Gbé Ní Ọ̀run
Kí lohun tí Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ nípa Jèhófà Ọlọ́run, Jésù Kristi, àtàwọn áńgẹ́lì olóòótọ́?
Ẹ̀kọ́ Tá A Rí Kọ́ Lára Àwọn Ẹyẹ Ojú Ọ̀run
Kì í ṣe pé àwọn ẹyẹ fi iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọ́run hàn nìkan ni, wọ́n tún jẹ́ ká ronú nípa àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù.
Lefèvre d’Étaples—Ó Fẹ́ Káwọn Mẹ̀kúnnù Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
Báwo ló ṣe ṣàṣeyọrí láìka àtakò sí?
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Mi Ò Ní Apá
Ọkùnrin kan ṣèṣe gan-an nínú jàǹbá burúkú kan, síbẹ̀ ó rí ìdí tó fi yẹ kó gbà gbọ́ pé Ọlọ́run wà.
Ohun Tí Bíbélì Sọ
Ṣé Ọlọ́run máa gbọ́ kó sì dáhùn àdúrà rẹ?
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Ṣé Ọlọ́run Ló Dá Èṣù?
Ohun tí Bíbélì sọ bọ́gbọ́n mu, ó sì tuni lára.