Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2022-2023 Tí Aṣojú Ẹ̀ka Máa Bá Wa Ṣe
Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà
Àwọn ohun tá a máa gbádùn ní àárọ̀ àti ọ̀sán àpéjọ àyíká tí aṣojú ẹ̀ka ọ́fíìsì máa bá wa ṣe.
Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nígbà àpéjọ náà.