Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé ti Ọdún 2020

Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn nípa iṣẹ́ ìwàásù àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kárí ayé láti September 2019 sí August 2020.

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2020

Ìròyìn ọdọọdún yìí máa jẹ́ kó o rí bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe sapá tó àti owó tí wọ́n ná sórí iṣẹ́ ìwàásù Ìjọba Ọlọ́run kárí ayé.

Ìròyìn Orílẹ̀-Èdè àti ti Ìpínlẹ̀ Ọdún 2020

Ìròyìn yìí jẹ́ ká mọ iye wa, iye àwọn tó ṣe ìrìbọmi, iye àwọn tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

O Tún Lè Wo

ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?

Wo bá a ṣe máa ń ka iye wa nínú àwọn ìjọ wa kárí ayé.

ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Lọ Láti Ilé Dé Ilé?

Kọ́ nípa ohun tí Jésù sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ pé kí wọ́n máa ṣe.

ÀWỌN Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ TÁ A LÈ LÒ LÓDE Ẹ̀RÍ

Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló fẹ́ mọ irú ẹni tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà jẹ́. Jọ̀wọ́, wo fídíò tí àwa fúnra wa ṣe yìí, kó o lè túbọ̀ mọ̀ wá.

NÍPA WA

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Mọ̀ nípa ẹgbẹ́ ará wa kárí ayé.

NÍPA WA

Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Níbi gbogbo kárí ayé làwọn èèyàn ti mọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọ́n máa ń ṣe fáwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́. Wo bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é.