Ìtàn àti Bíbélì
Àkọsílẹ̀ bí wọn ṣe pa Bíbélì mọ́, tí wọ́n túmọ̀ rẹ̀, tí wọ́n sì pín in kiri ṣàrà ọ̀tọ̀. Àwọn ohun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ń rí báyìí túbọ̀ fi hàn pé òótọ́ láwọn ìtàn tó wà nínú Bíbélì. Láìka ẹ̀sìn tí ò ń ṣe sí, wàá rí i pé Bíbélì yàtọ̀ sí ìwé èyíkéyìí mìíràn.
ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ
Ìwádìí Àwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Rí I Pé Ọba Dáfídì Gbé Láyé Rí Lóòótọ́
Àwọn alárìíwísí kan sọ pé ìtàn àròsọ lásán ni ìtàn Ọba Dáfídì, pé àwọn èèyàn ló hùmọ̀ ẹ̀. Àmọ́, kí làwọn awalẹ̀pìtàn rí?

Àwọn Ìtúmọ̀ Bíbélì
Àwọn Tó Túmọ̀ Bíbélì
Òótọ́ Ni Àwọn Ìtàn inú Bíbélì
Ìtẹ̀jáde
Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
Kí ni lájorí ẹ̀kọ́ tá a lè kọ́ nínú Bíbélì?