Orin 101—Ṣíṣiṣẹ́ Pa Pọ̀ ní Ìṣọ̀kan
Máa kọ orin yìí bí fídíò ṣe ń kọ ọ́, ó máa jẹ́ kó o rí pé àwọn èèyàn Jèhófà wà ní ìṣọ̀kan kárí ayé.
O Tún Lè Wo
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Sọ Bí Àwọn Àwòrán Yìí Ṣe Yàtọ̀ Síra: Eré Àpéjọ Àgbègbè
Fi àwọn àwòrán náà wéra. Kí lo lè ṣe tí wàá fi máa fi máa pọkàn pọ̀ ní ìpàdé?
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.