Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Gídíónì

Wa káàdì eré Bíbélì yìí jáde, kó o sì kọ́ nípa Gídíónì, ọmọ Ísírẹ́lì kan tó mọ ìwọ̀n ara rẹ̀ tó sì di jagunjagun tó nígboyà. Tẹ̀ ẹ́, gé e, ká a sí méjì, kó o sì tọ́jú rẹ̀.