Ìsọfúnni Ṣókí—Croatia
- 4,038,000—Iye àwọn èèyàn
- 4,687—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 57—Iye àwọn ìjọ
- 870—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
Zagreb, Croatia—Ẹlẹ́rìí kan ń fún ẹnì kan ní ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ ní òpópónà Ilica
Rovinj, Croatia—Wọ́n ń fi ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! lọni
Rovinj, Croatia—Wọ́n ń fi ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
Zagreb, Croatia—Wọ́n ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé? lọni
Zagreb, Croatia—Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìrètí tó wà nínú Bíbélì
Pula, Croatia—Wọ́n ń fi àṣàrò kúkúrú, Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la? lọni nítòsí gbọ̀ngàn ìwòran àwọn ará Róòmù àtijọ́