Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwọn Ohun Tó Jáde Láìpẹ́ Yìí

 

Ṣé Bíbélì Fẹ́ Ká Máa Bọ̀wọ̀ fún Èrò Àwọn Míì?

Ohun tí Bíbélì sọ máa yà ẹ́ lẹ́nu.

 

Bó O Ṣe Lè Yẹra fún Ọtí Àmujù

Àbá márùn-un tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀wọ̀n ara ẹ nídìí ọtí kódà tí nǹkan ò bá tiẹ̀ rọrùn fún ẹ.

Inú Rere Ṣe Pàtàkì Lójú Ọlọ́run

Ṣé ó yẹ kó o máa fi inú rere hàn sí gbogbo èèyàn. Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo ànímọ́ yìí?

Ìdí Tá A Fi Nílò Ọlọ́run

Kọ́ nípa bí a ṣe lè láyọ̀ kí ìgbésí ayé wa sì ládùn tí a bá sún mọ́ Ọlọ́run.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Mi Látorí Íńtánẹ́ẹ̀tì?

Ohun tó yẹ kó o mọ̀ àti ohun tó o lè ṣe láti dáàbò bo ara ẹ.

Tó O Bá Fẹ́ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù, Ó Yẹ Kó O . . .

Léraléra ni Jésù fi àwọn ànímọ́ mẹ́jọ yìí hàn jálẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀.

Alákòóso Wo Lo Máa Yàn?

Kí Ni Bíbélì Sọ?

 

Báwo Ni Ọdún Halloween Ṣe Bẹ̀rẹ̀?

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé látinú ìbọ̀rìṣà ni àwọn ohun tí wọ́n máa ń ṣe nígbà Halloween ti wá, ṣé ó yẹ ká kà á sí?

Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́?

Wàá rí ìdáhùn tó o bá jẹ́ káwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́.

 

Báwo Ni Àlàáfíà Ṣe Máa Wà ní Ayé?

Kọ́ nípa ìlérí Ọlọ́run láti mú àlàáfíà wá sí ayé nípasẹ̀ Ìjọba rẹ̀.

Ibo Lo Ti Lè Rí Ayọ̀ Tòótọ́?

Ìwé yìí á jẹ́ kó o mọ bí àwọn ìmọ̀ràn tó wà nínú Bíbélì ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.

 

Ọlọ́run Ìfẹ́ Máa Bù Kún Ẹ Títí Láé

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn nǹkan tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún ẹ, ìdí tó fi yẹ kó o gbà pé Ọlọ́run máa ṣe é àti ohun tó yẹ kó o ṣe kó o lè gba ìbùkún Ọlọ́run.